Eti oba nile, eti oba loko; eniyan ni i je be. Ati ri gbo bayii wi pe Osita Iheme ti n mura sile lati se igbeyawo pelu orekelewa obirin kan lati ilu Ghana. Bi o tile je wi pe bonkele ni won fi oro naa se, sugbon awon Yoruba so wi pe ba se n yo so naa la n yo gbo.
Ati igba ti ikeji Pawpaw ti oruko re n je Chinedu Ikedieze (Aki) ti se igbeyawo ni gbogbo awon ololufe re ti n reti ohun rere bi iyawo alarede lati odo tie naa.
A dupe fun Oluwa wi pe iyanu pada sele.
Ojo kerinlelogun osu kejo odun 1982 ni won bi Osita ni Ipinle Imo. Ifafiti ti Ipinle Enugun lo ti jade nibi to ti kawe gboye nipa Igbohun Safefe (Mass Communication). Odun 2011 ni Aare GEJ fi ami-eye MFR daa lola.
Bi ata ti wu ko kere loju to, ko si eni le fi raju. Osita tile le kere loju sugbon ogbon, imo, okiki ati aseyori re bi ti agbalagba ni.
Mo ba Osita yo, mo si ba dupe lowo Satiramoni Oba mimo.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment