Smiley face

Ayeye Ojo Ibi Fathia Balogun Pelu Awon Omoge Peperenpe

Fathia Balogun se ayeye ojo ibi re lo ba pate ariya lana ode yii. Gege bi a ti gbo, ati inu ile re ni faaji ti bere ko to di wi pe won gba ile itura Sheraton to wa ni Ikeja lo lati lo peperenpe pelu awon afenifere.

Fathia Balogun (eni ti o ti n je Fathia Williams bayii) pe eni odun marunlelogoji (45yrs) ni awon ore bi Moji Olaiya, Ronke Oshodi, Foluke
Daramola, Dayo Amusa, Sikiratu Sindodo ati aimoye ore ati ojulumo fi pejo lati ba fi ope fun Oluwa oba.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment