Smiley face

[Foto] Alakorun Oge Ti Won Fi Ayan Se


Alakorun oge awon obirin ti won fi ayan se. Bi o tile je wi pe ki i se ayan gidi, won kan se ohun elo esho naa gege bi ayan lasan ni.

Ayan je ohun kan to ri opolopo eniyan lara, opolopo obirin ni won si korira re bajebaje.

Ki lo wa le mu onise oge naa ronu ohun esho ti won se bi ayan gege bi eroja oge fun awon obirin?


A bi eyin le wo sorun ni?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment