[Foto] Aso To Ju Sanyan Lo Ni Iyawo Paul Okoye Fi N Dara Oge Nibi Eto Igbeyawo Won
Eto igbeyawo alarinrin waye lana ode yii laaarin Paul Okoye ati aya re, Anita Isama. Bi omobirin naa se n bo aso kan lo tun wo omiran, gbogbo aso to wo pata lo gbayi pata.
0 comments:
Post a Comment