Okunrin naa ki i se wi pe o ti ku patapata, igbadun ati faaji lo poju fun un lagbo Davido ni ilu Congo. Ko maa lo je wi pe alaye ti mu otin yo nibi to ti n jo Skelewu ni?
Eyin agbo ni Dafidi omo Adeleke eni ti a bi ninu osu kokanla odun 1992 si ilu Atlanta, Georgia ti foju kan okunrin naa to si bere ti i lati ya foto re.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment