Ko si ohun to dun ninu iroyin ife to ti n ladun tele to wa pada di ikoro. Awuyewuye oro naa ti wa lori afefe bi igba die seyin wi pe Wizkid ti da oro ife ru pelu olulufe re ti n je Tania Omotayo eni ti Wizkid feran lati maa pe ni 'T Bebe'.
A gbo wi pe won ko si papo mo bayii, sugbon oro naa n semi bi ki n pada wa to baya lati so fun yin wi pe won ti pari ija to wa laaarin won. Ti Edua oke ba se bee, Olayemi Oniroyin; maa tun wa kede re fun araye.
Igbeyin ewuro ni i ladun bi oyin. Igbeyin eni ba je asala tan to tun mu omi ni i koro bi Jogbo. Aye wa ko ni koro o! Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment