Smiley face

"Osu Mokanla Pere Lo Ku Fun Irawo PDP Lati Tan" Talo So Bee?

Minisita fun olu ilu Nigeria to je Abuja nigba kan ri, Malam Nasir el-Rufai ti so nibi ipade awon egbe PDP to waye ni Kaduna lojo Abameta to koja yii wi pe osu mokanla pere lo ku fun egbe PDP lori aga isakoso. Oni leyin eyin ni APC yoo si maa tesiwaju ninu isejoba ile Nigeria.

Malam Nasir el-Rufai to je igbakeji fun akowe agba fun egbe APC ni a tun gbo wi pe o seese ko gbe apoti idibo fun ipo gomina ni Ipinle Kaduna. el-Rufai fun ra re soro lori aheso oro naa, e gbo ohun ti baba kekere wi:

"My priority as the deputy national secretary is to ensure that, APC is a very strong party in Kaduna State and other parts of the country. And the question of contesting for office will be
determined by the party at the appropriate time".
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment