Smiley face

Ayẹyẹ mọmi-n-i-mọọ: Ojo ti mo ko awon ebi mi lo pada awon ebi iyawo mi

Ti mo ba lo padanu awon foto yii yoo ti dun mi ju. Bi o tile je wi pe mo ni eyi ti won ti te lowo. Sugbon ko si ohun to buru ti mo ba gbe die sibi. 


Oni ojo kejilelogun osu keta odun 2014 ni mo ko ebi mi lo mo ebi awon iyawo mi nipinle Ogun. Ojo nla ni ojo naa je fun mi ninu igbesi aye mi. 

Mo dupe lowo awon ebi mi ati ebi iyawo mi fun aduroti won. Awon ore mi naa nawo nara lojo naa. Mo si tun dupe lowo ololufee mi, Kehinde Olaitan. Ayo mi. Titi aye ni maa ma nife re. Amin  


































































































































































































































Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment