Sebi ibi to ba wu efuufulele ni i dari igbe si, ibi to ba wu olowo ni won feru ti won se. Ara to wu Dafidi omo Adeleke ni fi owo dollar da.
Bee oro awon agba ni wi pe ajoje ko le dun ti enikan ko ba ni. Adura mi ni wi pe ki Edumare fi owo sore gbogbo wa.
E dakun, e samin adura.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment