Smiley face

'Obesere N Fi Iku Deru Ba Mi' - Obirin Ti Obesere Fi Tipatipa Ba Sun

Omobirin to kede wi pe Abass Akande Obesere fi tipatipa ba oun ni ajosepo, Olanike Olaiya tun ti ke gbajari wi pe omokunrin olorin naa tun leri wi pe oun yoo seku pa oun ti oun ko ba ko lati maa fi oro lo awon oniroyin. Gege bi oro omobirin naa, oni o jo bi eni wi pe won ti fe fi owo agbara gba oun loju nitori ohun se akiyesi wi pe awon olopa ti won da si oro naa ti n gba abetele eleyii to ti n mu oro enu won yato. Omobirin naa ti sa lo ba yii latari aabo emi re ti awon kan ti n lepa.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment