Smiley face

Akitiyan Awon Akinkanju Lori Omi Nibi Won Ti N Wa Oko Ofurufu MH370 Ti Ilu Malaysia

Awon Yoruba ni bi ina ko ba tan laso eje kii tan leekan naa. Akitiyan awon onimo ijinle si n lo lowo nipa ati se awari oko baalu ofurufu MH370 ti ilu Malaysia to poora lojiji . Baalu ti awon onwoye so wi pe oseese ko je wi pe inu okun lo bale si ti di ohun ti enikeni ko le so pato ibi to wa titi di akoko yii.
 
 
Awon eniyan ti oro kan ni ilu Malaysi n fi joojumo banuje, a si gbo wi pe o seese ki Barack Obama yoju si ilu naa laipe.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment