Smiley face

Aworan Kayeefi Lati Ilu Londo

Orisiirisii ara ni ilu London!
 
Okunrin kan ti oruko re n  je Sam Jacob lo ya aworan kayeefi yii ni igboro London nibi to ti ri arakunrin to so okun mo pepeye meji to si n mu won je kiri bi eran ewure.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment