Awon Yoruba bo, won ni bi omode ko ba ba itan dandan ni ko ba aroba, aroba si ni baba itan.
Olayemi Oniroyin, mo ti lo ba awon agba nipa wi pe kini AROBA je gan-an.
Gege bi alaye awon agbalagba ti won mo idi eeta, won ni Aroba ni ohun kan ti n se apeere itan to ti sele seyin tabi ohun kan ti eniyan le toka si eleyii to romo itan igba iwase tabi ohun to mu ni ranti isele to ti sele koja nigba lailai.
Bi iru isele bee ko tile soju omode, ami tabi apeere ohunkohun to so nipa itan naa ni o je bi aroba. Iru apeere nnkan bee ni Opa Oranmiyan ti mbe ni ilu Oyo.
Nibayi awon oluwadii ti se awari awon ohun ija ogun eleyii ti won lo ninu Ogun Agbaye Eleekeji ninu igbo kan ni ilu Russia.
Aroba ni eleyii je fun awon eniyan ti won ko mo igba ti Ogun Agbaye Eleekeji waye.
Ogun Agbaye Eleekeji waye laaarin odun 1939 si 1945.

0 comments:
Post a Comment