Ni agbegbe Kuntu/Agbo-Oba ni omo osu metadinlogun kan ti oruko re n je Abdulhafeez ti seese mu kerosiini to si see bee jade laye.
Iya omo yii ti n je Iya Luku lagbo wi pe kerosiini ati elubo nii ta. Okan ninu awon omo re lo kiri kerosini pada wale lati ikiri pelu igo kerosiini meji to seku.
"I left two half-filled bottles outside
where I cooked and when their father,
who had been out returned, he said
the half-filled bottles should be properly kept.
But before I could go put them away, his sister had opened the two half-filled bottles for him.
"When I came out, I saw my son in a
terrible condition. He was writhing in
pain and I shouted for help. We tried to give him palm oil but it took some
minutes to pass it into his mouth," - Iya Luku
Won sare gbe omo yii lo si ile iwosan sugbon epa o gboro mo pelu bi omo naa se n yagbe titi won fi de ile iwosan. Oju ese naa ni ahon omode yii bere sini dudu ti omo naa si n wo baibai ko ti di wi pe o je Olorun ni ipe.
Gege bi oro iya Luku, o ni omo ti ku lowo oun ri, o ni sugbon eleyii tun ja oun laya gidi o si tun ba oun lokan je ju lo.
Home / Uncategories / "Ahon Re Bere Sini Dudu, Oju Re N Wo Baibai, O Si N Yagbe Kikan-Kikan Ko To Di Wi Pe Oku" - Omo To Mu Kerosiini Ni Ilu Ilorin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment