Atejade lati ile ijoba ile Amerika ti bu enu ate lu ipakupa awon eniyan ti n waye ni Bentiu to wa ni guusu ilu Sudan.
Ija abele yii lagbo wi pe o mu emi aimoye awon eniyan lo eleyii ti oku won ti di ounje fun awon eye oju orun bayii.
Gege bi iwadii olayemioniroyin.com, aimoye oku awon eniyan bi igba lo kun oju opopona bi panti, dukia ti enikeni ko le so iye won si ti sofo danu bi omi efo.
Lati ile funfun balau to je ti ijoba Amerika ni won ti n pe fun idaduro ohun ti won se apejuwe re gege bi idaniloro ni n waye ni ilu Sudan.
Die lara oro White House ni yii:
"We are horrified by reports out of South Sudan that fighters aligned with Machar massacred hundreds of innocent civilians last week in
Bentiu," atejade lati White House.
"Images and accounts of the attacks shock the conscience: stacks of bodies found dead inside a mosque, patients murdered at a hospital, and
dozens more shot and killed in the streets and at a church - apparently due to their ethnicity and nationality - while hate speech was broadcast on
local radio.
"Bulldozers have buried the dead in mass graves, and the number of people seeking protection at the UN camp in Bentiu has grown from 8,000 to more than 22,000 in two weeks.
"These acts of violence are an abomination. They are a betrayal of the trust the South Sudanese people have put in their leaders."
Nigba ti awon eniyan dudu ba n fi owo ara won pa omo iya won nipakupa, ti onile n fi owo ara re wo ile ara re, ti awako si n wa oko ara re seyin, igba wo gan-an ni idagbasoke fe waye?
Ijekuje, ojukokoro, imotara eni nikan ati iwa odaju awon olori ile adulawo je awon ohun kan pataki ti n mu ina idagbasoke awon eniyan dudu jo ajo reyin nigba ti awon alaise si n ku iku ibanuje kaakiri Afirika.
Olayemi Olatilewa ni oruko mi, ilu Sudan ni mo ti lo mu iroyin mi wa, o si damiloju wi pe olayemioniroyin.com naa le si n ka...
E ku ikale!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment