Ijamba oko oju irin waye lana ni guusu ila oorun Democratic Republic of Congo nibi ti awon eniyan bi metadinlogoji ti pare patapata loju ese.
"Thirty-seven people have died, but the police fear that there will be more," oro okan ninu awon agbe fun ijoba.
Oko oju irin to ko eru ati awon ero la sagbako ijamba ni agbegbe Likas to wa laaarin Lubumbashi ati Kolwezi.
"Evidently the train was going too fast, the driver came to a curve and had to break suddenly leading to the accident," Kazadi.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment