Smiley face

Fayemi Ta Fayose Laya Loju Gbogbo Aye

Gomina Kayode Fayemi ti Ipinle Ekiti to tun un mura ati dije ipo gomina ninu osu kefa odun yii labe egbe oselu APC ti pe akegbe re, Ogbeni Ayodele Fayose nija lati wa salaye fun gbogbo aye to ba je wi pe lotito ni eto eko ipinle naa duro soju kan lati igba ti Fayose ti kuro loye gege bi oro re.


Eniyan ti yoo puro ni yoo wi pe eleri oun wa lajule orun, Kayode ti ran Fayose to je alatako re labe egbe oselu PDP nise lati lo wo akolesile WEAC nipa bi awon akekoo se se nigba aye Fayose ati igba tuntun ti oun lo lowo yii.

Kayode se alaye ara re gege bi Omowe to mo pataki eko eleyii ti enikeni ko le ro ise ribiribi ti oun ti se nipa eto eko ipinle naa danu.

Olayemi Oniroyin, ko maa dabi eni wi pe enu mi dun ju, eyin naa e gbo ohun ti gomina so:


"So, there is a difference between what I can tell about education and what someone who doesn't know the
essence of education will tell you.

"Go to the West African Examinations
Council's office and check the trajectory.

"Go and see the records we have
achieved in the last three years. Ekiti
has produced good results consistently.

"I don't deal with opinions, I deal with
facts because facts are sacred, opinions are free; anybody can say
what he/she likes.

"I challenge my good brother, Mr Ayo
Fayose to a debate on the academic
records when he was the governor and what obtains now that I am governor.

"You can check out the entire parameters. When he was governor,
teachers were earning N7,500
minimum wage.

"There was no rural teachers' allowance. No core subjects allowance.
No capacity building programme as we are doing presently.''
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment