Smiley face

[Foto] P-square N Jaye Bi Oloba ni St. Lucia

P-square korin bee ni won si lulu ni Saint Lucia Jazz & Art Festival to waye ni ilu St. Lucia.

Igba won sise tan, awon naa duro se faaji ara won ni Pigeon Island to wa ni National Landmark ni ilu St. Lucia.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment