Awon omobirin bi ogorun ninu awon omo bi igba ti Boko Haram jiko salo ni olori awon Boko Haram, Abubakar Shekau ti se afihan won ninu fidio tuntun eleyii to jade lonii ojo Aje(12/5/14).
Ohun ti omokunrin naa so ni wi pe oun ko ni tu awon omo naa sile ayafi ti ijoba apapo ba le tu awon omo Boko Haram to wa lewon sile.
Omokunrin olori awon alakatakiti esin Islam yii tun so wi pe gbogbo awon omo naa ni won ti di musulumi ododo bayii.
Okan ninu awon omobirin naa si jeri si wi pe onigbagbo kristeni ni oun tele, sugbon oun ti n kirun wakati marun-un bayii.
Oniroyin BBC to wa loke oya, John Simpson so wi pe ko daju wi pe awon Boko Haram n fi iya je awon omo naa pelu bi won se joko lalafia. Ati wi pe Boko Haram setan lati tu won sile ti ijoba ba le se oun ti won fe.
E wo fidio naa [NIBI]
Home / Iroyin /
Oro To-N-Lo-Lowo
/ Iroyin Pajawiri: Boko Haram Ti Se Afihan Fidio Tuntun Awon Omobirin Ti Won Jiko Salo
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment