Awon Yoruba loni omo eni ku, o san ju omo eni nu lo. Ati wi pe ti eda ba n sare ki oju ma tini, ti oju ba ti teda, ere toku ti eda o maa sa ni ki iku ma mu lo.
Nipa oko ofurufu baalu ilu Malaysia MH370 to poora, o dabi eni wi pe ilakaka ati se awari baalu naa ti wa sopin loni pelu bi oko oju omi kankan soso to ku lori omo to je ti ilu China se pada wale pelu suuru.
Iroyin ti a gbo ni wi pe oko oju omi naa yonu lo fi pada wale. Sugbon ero awon eniyan ni wi pe ise naa ti su awon akosemose ti won wa ni won fi dabi ogbon bee.
0 comments:
Post a Comment