Smiley face

Leyin Odun Kefa Ti Julius Agwu Ti Se Igbeyawo


Oni lo pe odun kefa ti Julius Agwu ti se igbeyawo alarinrin pelu iyawo re. Odun 2008 (May 31st 2008) ni won so yigi awon mejeeji niwaju Oluwa. Edua Oke si ti fi omo meji saarin awon mejeeji. 

Olayemi Oniroyin, mo ba won dupe, mo si gba adura wi pe adun ko ni tan ni ile won.Amin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment