Smiley face

Awon Okunrin Bi Mejidinlogoji (38) Ba Omo Odun Meedogun Sun Lojo Kan Soso Ni Malaysia

Awon okunrin bi mejidinlogoji (38) lagbo wi pe won fi tipatipa ba omobirin omo odun meedogun (15) lajosepo fun aimoye wakati ninu ile kekere kan to wa ni abule kan ni Kelantan ni ilu Malaysia. Awon olopa ti ri awon metala (13) gbamu ninu awon onise ibi naa. 

Ohun ti a si gbo ni wi pe omokunrin omo odun metadinlogun kan lo dogbon tan omobirin naa si owo awon eniyan ibi wonyii.  Atejade awon olopa ni wi pe o ti pe ti awon eniyan ika naa ti n se ise ibi owo won sugbon ti awon eniyan abule naa ko je ki awon agbofinro mo nipa ohun ti n lo. 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment