Smiley face

Omoge Onibadi Olokiki Amerika Gbe Ara Mii Yo Ni Ilu France

Kim Kardashian , omoge onibadi olokiki ilu Amerika si wa ni ilu France ati oko re Kanye west pelu bo se ku die ki eto igbeyawo won wole de.  Ara oto tunntun ti omobirin onibadi olokiki naa gbeyo lonii ni bo se n kaakiri igboro lai wo komu.  

Gbogbo agbalumo to wa labe aso re ni awon omo aye fi n se fiimu wo lonii. O si dabi eni wi pe iyawo tuntun naa ko gbese ran enikeni.





Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment