Smiley face

Osama Bin Laden Ko Lo Bi Boko Haram" Ilu Amerika

Latari alaye Aare Goodluck Jonathan nibi ipade to n lo lowo ni ilu France wi pe awon omo Boko Haram je eka awon iko al Qaeda ni ile Amerika ti tako wi pe ko ri bee rara.

Won ni iko Boko Haram daduro loto ni, ko si ye ki Aare Naijeria koju won pelu ero wi pe omo leyin Osama ni won je.

Won ni bi o tile je wi pe ina kii deede gori odo lai lawo. Ati wi pe eegun ti n jo lori omi, onilu re wa labe odo ni.

Asoju ile Amerika fi da wa loju wi pe ohun to daju ni wi pe awon kan wa ti won se iranlowo fun Boko Haram eleyii to n mu won maa sebi alagbara

"Boko Haram is its own terrorist group, and the United States has designated Boko Haram as a Foreign Terrorist Organisation.

In this day and age, there is probably no terror group that does not have some links somehow, even if tenuous, to some other organisation.

But for the most part, we treat Boko Haram as its own terror organisation.
"
Oro yii lo jade lati enu Tina Kaidelow to je asoju US State Department Counterterrorism.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment