Smiley face

Won Ti Wu Oku Okunrin To Ha Monu Saare Ni Ipinle Osun

Won ti fa oku okunrin to n gbiyanju lati ji ori oku oloku ge salo ni ilu Ilobu to wa ni Ipinle Osun. Odun merin seyin ni won ni iya naa ti ku, oruko re si ni Sinatu. Abdulahi ni oruko okunrin to n gbiyanju lati ge ori oku iya naa salo, okan ninu awon omo adugbo si ni pelu.  Boya eyin ko ti ka iroyin naa tele, e le ka  ekunrere iroyin naa
[NIBI]  
Awon ogun abenugongo ti Abdulahi n lo ni yii lati fi se ise ibi



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment