Smiley face

Rihanna Se Bebe: Irun Ibile Adulawo Ati Aso Ti N Mu Awon Okunrin To Si Pata Ti Doge

Bere lati ibi aso Rihanna debi irun ile adulawo to se sori, gbogbo re pata ni won lo gbayii nibi ami eye iHeartRadio Music Awards  2014 to waye ni Los Angeles l'Ojobo to koja yii nibi won ti fi ami eye da a lola gege bi onkorin to gbamuse julo fun odun 2014.

Oro Rihanna re e nigba ti won gbe ami eye naa le lowo tan;

“I know I’m a pain in the ass, but it’s worth it because we got the biggest award of the night!”




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment