Ojo kerin osu kinni odun yii ni Annie aya Innocent Idibia bi omo re, Olivia si ilu Amerika. Omo naa ti n dagba eleyii to je bi idunnu fun un, sugbon ko sai ranti awon omobirin ti awon Boko Haram jigbe salo ati iru ibanuje ti yoo wa lokan awon obi won.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment