
Ile iwosan kan ni ilu Ilorin la gbo wi pe won koko gbe Alh Waheed Ariyo olorin musulumi lo nigba ti ara re ko ri bo se ye ko ri. Isele naa koja agbara awon dokita ilu Ilorin ni won ba sare gbe lo si ile iwosan ijoba apapo to wa ni ilu Ibadan,UHC. Ile iwosan naa ni okunrin naa pada dake si lana ojo Eti to koja yii.
“He went to Ilorin for a house warming ceremony when he suddenly took ill. He was taken to an hospital for treatment but was referred to UCH where he died this morning (2/5/14),” Alfa Raheem to je ore Alh Ariyo
Won ti sin okunrin naa ni ilana musulumi lana ode yii ni ile re to wa ni Ijoko,Ijoba Ibile Ifo, Ipinle Ogun.
Eni odun metalelaadota [53] ni i se ki olojo to de.
K Oba Allah ba wa te si afefe rere. Amin
0 comments:
Post a Comment