Smiley face

P-square: Fidio Orin Testimony Ti Wa Lori Ina Ni Ilu South Africa

Ise n lo, ise o duro fun awon omo ibeji olorin Nigeria nipa ati gbe fidio orin won ti won pe akole re ni Testimony. Ara foto fidio ti won n ya lowo naa lo wa loke yii ni ilu South Africa.


Testimony....Je m'apelle chop money. #MusicVideoShooting


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment