
Enikeni ko tile le so iru fiimu pato ti AKON n ya lowo, sugbon ohun to daju ni wi pe omo okunrin olorin ti a bi lodun 1973 n sise lati gbe fiimu kan jade pelu akiyesi atejade ori Facebook re. Awon Yoruba si bo, won ni eni a n gbe iyawo bo wa ba kii gbe ori iganna woran.
E ku oju lona!
0 comments:
Post a Comment