Gomina Ipinle Eko nigba kan ri, Sir Michael Otedola ti dagbere fun ile aye loni ojo karun-un osu karun odun 2014 leni odun metadinlaadorun (87).
Odun 1992 si 1993 ni Micheal Otedola fi di ipo Gomina Ipinle Eko mu labe egbe oselu NRC.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment