Owo mi ti te fidio awon Boko Haram to jade lonii, e gbo ohun ti won so:
"Emi ni mo ji awon omo yin gbe sa lo. Maa si ta won loja ni, ni agbara Allah. Oja mbe ti won ti n ta awon eniyan. Allah lo ni ki n ta won. O pa mi lase lati ta won. Maa ta awon omo obirin yin, maa ta awon omo obirin yin."
Olori awon Boko Haram ti oruko re n je Abubakar Shekau lo so eleyii jade lonii ninu fidio tuntun ti won fon sori ayelukara. Ede Hausaa lo fi so awon oro naa.
#BringBackOurGirls
0 comments:
Post a Comment