Ko si ibi ti Boko Haram ko si lagbaye, oruko ti won je lo yato si ara awon. Awon iko ologun alakatakiti esin Islam ti ilu Somalia ti ise owo won ko yato si Boko Haram ti ilu Nigeria sugbon ti won je Al Shabaab lagbo wi pe won ya wo abule kan ni ilu Kenya ti won si bere si ni pa awon eniyan ti won kii se musulumi ni ale ana nigba ti awon eniyan n woran boolu agbaye to n lo lowo ni ilu Brazil.
Aimoye awon eniyan ni won pa ni agbegbe kan ti nje Mpeketoni to gbenu le bode Kenya ati Somalia.Yato si emi awon eniyan ti won fi sofo, aimoye dukia ni won ju ina si. Bi ina se n jo naa ni awon ina naa tun korin kiri gbogbo ilu naa titi ti ile fi mo.
E ja ka gbo die lenu awon ti isele buruku naa sele si:
'They came to our house at around 8pm and asked us in Swahili whether we were Muslims,' eyi ni oro Anne Gathigi eni ti isele naa soju re. 'My husband told them we were Christians and they shot him in the head and chest.'
Mo toro aforijin wi pe e ko ri mi lojude. Mo ni isoro die pelu oju opo olayemioniroyin.com ni. Sugbon awon onimo ero ti n ba mi se ayewo le lori lowo. Titi di igba ti atunse naa yoo fi pari, maa ro yin ki e maa lo olayemioniroyin.blogspot.com lati fi maa ka awon iroyin to gbamuse. E se gan-an.
Oga mi we are always wif u.
ReplyDeleteThank you so much. #Onelove
ReplyDelete