Kosi ohun ti ife ko le so eniyan da. Elomii, ife le so di akewi osan gangan. Amo nipa ti oko Toyin Aimakhu, oni ise oge irun ni ife re sodi bayii. Ife dun, ife larinrin.
Ninu iroyin mii eleyii ta le pe ni ife osan gangan to n gbona sugbon ti kii se iru ti Toyin ati oko re o. A ni Ogbeni Kofi Alawada...ennn... Sebi e mo? Okunrin naa ti lo gbe ohun to ju lo bayii.
Buredi nla ti Kofi tun je ni yii. Abalajo ti a ko fi ri okunrin naa lode ariya bi ti igba kan mo. Eniyan o gbodo maa je iru nnkan nla bayii ko ranti ise mo. Abi? Ise eleyii gan-an ju ise lo. Erkk
0 comments:
Post a Comment