Si gbogbo awon ololufe Funke Akindele, won ni kesekese lasan leri seyin, kasaksa mbo bayii baba kesekese. Sugbon won ko ti fun mi lase lati be saye.
Sugbon pelu aworan yii, odaju wi pe oju ogun ni Funke Akindele n lo. Nje iru oruko wo ni a wa le fun-un pelu imura re ninu fiimu yii?
O ya, fun loruko kan?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment