Bi ojumo ba se n mo ni awon ohun ti ko sele ri yoo maa waye ti yoo si dabi kayeefi loju omo eniyan. Sugbon pupo iru awon nnkan wonyii ni i se afihan agbara Olorun Oga ogo.
Arakunrin Wim Hof latii ilu Holand ti wo inu iwe aramanda olokiki agbaye, Guinness Record Book nipa wi pe okunrin naa le wa ninu yinyin fun aimoye wakati ti eje re ko si ni di papo.
Igba ti okunrin yii se alaye agbara re, awon eniyan ko gbagbo (paapa ju lo awon dokita onimo isegun). Sugbon lojo kan, won gbiyanju lati dan agbara re wo(tabi ka so wi pe ebun to ni). Won gbe gorodoomu nla kan si arin ita gbangba pelu opolopo yinyin (ice). Okunrin yii wo ilu yinyin fun aimoye wakati bee ohunkohun ko sele si.
Ebun arakunrin yii ti so di olokiki bayii eleyii to mu oruko re wo inu iwe akosile awon akoni agbaye.
E gbo ohun ti okunrin naa so nipa ara re:
'I feel like I can control my own body as if I have a thermostat that I can adjust when I need to. The most challenging record was climbing Everest in just a pair of shorts.Swimming beneath the ice and not finding the hole back was quite a frightening experience too. But I'm confident enough because I know what my body can cope with. It is a lifestyle that I have chosen to take therefore I train everyday wherever I am. I don't bother with gyms, I just workout where I happen to be whether it's in the garden or at home.It's a great honour to have the nickname of Iceman, it makes me feel very proud of my achievements.'
Iroyin mii taa tun gbo ni wi pe awon onimo ijinle ti bere si ni fi ara okunrin naa se iwadii imo ijinle to ki. Abajade iwadii won nii wi pe okunrin naa le ran agbara jade lati inu opolo re eleyii to dabi eni wi pe o n pa ase fun awon eya ara re yoku lati wa ni ipo to fe ki won wa. Won ni ti okunrin yii ba ti wa ninu yinyin, opolo re yoo pase fun ara re wi pe ko maa gbona tabi ko maa loworo (warm). Eleyii lo si n fun ni anfaani lati wa ninu yinyin fun igba pipe.
Won tun lo so okunrin naa si agbegbe olotutu lai wo ewu, won si n fi baalu so lati oke
0 comments:
Post a Comment