Awon orekelewa obirin. mmmmmmh!
Tani ni eyin feran julo ninu awon mejeeji?
Ninu iroyin mii to tun te wa lowo ni ayeye ojo ibi ti Mercy Aigbe se fun omo re ni ile iwe re. Jumon pe omo odun merin ni iya re ba ra akara oyinbo oloyin lati lo gbe pade re. Ni oruko mi, ati gbogbo igbimo Olayemi Oniroyin ni a ki Juwon ku orire ojo ibi re. Ewe iyeye igba ni. #HBD
Mo tun fe fi to yin leti wi pe Olayinka Ayefele ti pade de lati ilu London. Boya eyin ko ti ka iroyin Ayefele ni ilu London, e le ye wo [
NIBI]
0 comments:
Post a Comment