Smiley face

Omobirin Irawo Onitiata Ti Si Gbogbo Idi Tan Fun Gbogbo Aye

Tonto Dikeh 
Omobirin onitiata ede oyinbo ti oruko re n je Tonto Dikeh lo gbe aworan yii sori ero ayelukara alatagba re pelu akole yii:

“Dare me if you can go this far” " 
Sugbon oju ese naa lo tun ti pa aworan naa re.


Olayemi Oniroyin, meji-meji ni iroyin mi, Iroyin mii to tun jo iru eleyii ni ti Maheeda omo olorin te e ti mo tele pelu aworan to le mu ni je gbese osise alajo tankasu. Sugbon sa, awon aworan  ote yii tun gaayata gan-an ni o.

E joo, e maa wo nigba ti iyawo yin ba wa nitosi o. E si maa daruko Olayemi Oniroyin rara ti oka yin ba ti fo, nitori mi o mo ohunkohun nipa re rara. errk
Maheeda 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment