E ma lo ro wi pe eyin nikan le wo ifesewonse ere boolu agbaye to waye laaarin Nigeria ati Bosnia nibi ti Osaze ti dana sun won pelu amin ayo kan si ofo. Inu Aare dun gan-an lana o pelu gbogbo ohun to sele lati aaro titi ti ile fi su. Koda, iyan Ekiti ni Aare Goodluck je sun.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment