Smiley face

Asiri Baba Olomo Merin Tu Nibi To Ti N Gba Nombe Omoge Ni Ilu Brazil

Baba olomo merin to je ololufe egbe agbaboolu England ni kamera awodi oke awon oniroyin ti gbe nibi to ti n gba nomba omoge ilu Brazil kan nigba ti ere boolu n lo lowo. Sugbon okunrin ti oruko re n je Carl Wenz so wi pe oro naa ko ri be rara, oni foto lasan ni awon jo n ya.


 'The girl in the photo asked if she could have a picture taken with me, of which I said yes, her brother took the photo and I am seen looking at it on her phone.'
Awon ebi okunrin naa ti fesi rannse lati ori ayelukara si awon oniroyin ti won ko koju mo iroyin ere boolu agbaye ti won fi ran won to je wi pe baba onibaba ti n se faaaji ara re ni won fi kamera ya kiri ori papa.

E gbo ohun ti won so:

He's in a long-term relationship and would consider the interest generated by the picture hilarious. He's a massive football fan and follows England all across the world. think he's even shut up the shop front while he is away. I know Carl as a proper family man so I don't think there's anything dodgy about the picture.He wouldn't save up to travel halfway across the world just to get a Brazilian girl's number. I bet he was showing her pictures of his kids.' 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment