Smiley face

Kini Gomina Ipinle Oyo So Nipa Arisekola Alao?

Eni odun mokandilaadorin (67) ni Aare Musulumi ile Yoruba,  Alhaji Abdul-azeez Arisekola-Alao ki iku to mu lo laaro ojo Aje to ko ja yii ni ilu London. Ola ode yii ni won yoo si gbe agbaoje onisowo naa wo ilu Nigeria lati sin ni ilana musulumi. 



Gomina Ipinle Oyo, Abiola Ajimobi ti ba awon idile olooogbe kedun, o si saleye iku Aare Musulumi ile Yoruba  gege bi adanu nla fun ile Nigeria lapopo. Die ni yii lara oro Gomina:

"Aare cannot die as those who lived the kind of life he lived, with imprints in the lives of millions of people, never die. He lived a life that was devoted to the lives of others. It is indeed the end of an era for us in Ibadan and Nigeria in general.”

Gomina tun fi kun un wi pe musulumi ododo ni Alhaji Azeez, o si tun se alaye re gege bi eniyan to lawo gidi gan-an, alaanu mekunnu.

"Uncle Arisekola-Alao was an upright, consistent and principled man. He called a spade by its name without minding whose ox was gored. 
"Aare Musulumi of Yorubaland was also a pillar of support to our administration whose wise counsel had helped tremendously in the success story so far recorded by our government.’’ 


Wayio, Gomina Abiola Ajimobi ti kede ojo Eti ti n bo yii gege bi ojo isimi lati fi bu ola fun Aare Musulumi to lo ba Oba Allah loke. Ki Olorun oba ba te oloogbe si afefe to dara. Amin.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments: