Smiley face

Omu Nla Bi Ogede Agbagba Fo Yangayanga

Kim Brockhurst, eni odun mokanlelaadota (51) lo na owo ti isiro re n lo bi milionu kan owo naira (1M) lati so omu aya re di shikishiki. Sebi awon Yoruba naa ni won ni omu shikishiki ni iyi obirin. Gege bi alaye iya yii, oni oun fe ki omu oun durosoke bi eru ti mbe laya Ronke Oshode Oke, ko si tun ta daada bi isu ori ebe to ni ajile ninu daada. 

Igba ti awon dokita gbe opele sanle, won ni 'pure water' ni Ifa so wi pe oro re je mo. Won la omu obirin yii won si ko ora pure water nla meji sibe, sugbon ayederu ni orisii eroja ti won lo fun un. Ojo kan ni ora piowota yii fo, to si dun gbamu. Awon eniyan tile koko sebi boya Boko Haram lo ju ado oloro, a fi igba ti won ri omi ti n sun jade laya sisi mama. 
Iya yii ba  awon oniroyin soro. E je ka gbo ohun ti iya naa wi ko maa di wi pe Olayemi Oniroyin lo doju oro ru bi t'Onibode Lalupon:

'I was really flat chested and I wanted a bit more bounce. So I saved up for the surgery hoping it would give me a nice confidence boost. But I ended up with these big heavy breasts - much bigger than I’d asked for.
But it got worse when my breasts slowly went out of shape - it was a terrible time. Soon I had a big dent in my right breast and the implant on the left just exploded - leaking the implant’s industrial strength silicone into my breast tissue.’ 
'Orisa boo le gbe mi saa semi bo o ti ba mi' ni rekoodu orin tuntun ti iya yii n ko seti awon dokita alaso funfun bayii. A se lotito ni wi pe bi eniyan ko ba dan ile oko meji wo ko le mo eyi to wa OK. Sodiafoo, itelorun ni ifokanbale ati alaafia.

Olayemi Oniroyin Agbaye ni won pe mi nigboro. Bi e ba se n tele mi lori @OlayemiOniroyin lemi naa n follow yin bi oromadie se n tele iya e lori twitter. 

E ku Ikale!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment