Smiley face

Akin Omo Akin Nilu London Se e Wa o?

[Eni to wa ni aarin] Akindele Akinsanmi ti gbogbo eniyan mo si Akin omo Akin naa yoju sibi ayeye Notting Hill Carnival to ti bere lana ni ilu London.

Akin omo Akin ni alase ati oludari Surprise Radio to wa ni ilu London. Aimoye awon sorosoro ori afefe ni ile Yoruba ni won maa seto lori radio naa nigba ti won ba wa ni ilu London. Die lara awon sorosoro naa ni Ambrose Somide, Kola Olootu, Yemi Sonde, Yinka Ayefele abbl.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment