Daddy Showkey, irumole Ajegunle wa lara awon olorin ti won
sere fun awon omo Naija lana ni ilu London nibi ayeye Notting Hill
Carnival ti n lo lowo.
E maa gbagbe wi pe Wizkid naa ti
wa ni nilu London bayii. Aimoye awon eniyan lati Nigeria ni won wa ninu
baalu lowolowo bayii ti won lo si ilu London lati lo se faaji.
Eyin naa e tete se kia ke e bawa. Ilu London n dun yungbayungba bee si ni ko si Ebola rara.
0 comments:
Post a Comment