Iwe Iroyin Punch ti ile Nigeria ti setan lati gbe Iwe Iroyin Vanguard, Sun ati Thisday lo si ile ejo latari atunte iroyin kan eleyii to tako Aare Jonathan ti won ni Punch lo gbe jade, eleyii ti Punch so wi pe iru iroyin bee ko jada lakata awon rara.
Awon oloselu kan ni won lo wa nidi isele naa.
Sugbon bayii, Punch ti n leri lati gbe awon ile ise iroyin naa lo si ile ejo ayafi ti won ba tuuba.
0 comments:
Post a Comment