Smiley face

A Wa Ko Salo Fun Boko Haram, A Lo Sempe Ni- Awon Omo Ologun Nigeria

Awon omo ologun ile Nigeria ti tako iroyin to jade wi pe awon omo ologun Nigeria ti won wa ni Ipinle Borno ti salo si ilu Cemeroon nigba ti won ri idagiri awon omo iko ogun Boko Haram.

Gege bi atejade ti won fi sita, won ni awon o sa rara, awon sempe ni.

Won si n kilo fun awon oniroyin lati yee so ohun ti oju won ko to. Won tun salaye wi pe iru iroyin bee le tun maa fun awon omo Boko Haram lagbara lati maa sapa bi itan ki won si maa saya bi eyin.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment