Sebi ilu Amerika ni Dayo Adeneye wa lati nnkan bi ose melo kan seyin. Igba to gbo wi pe Notting Hill Carnival maa bere ni ilu London lo sare lo wo baalu. A se tori idi nla yii ni D1 se wo ilu London. Igba ti omoge naa gbe sun mo o, n se ni gbo netiwooki ori re daru patapata. Chai!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment