Friday Akpan, eni ogota odun (60) ti n sise asobode la gbo wi pe o ki omo oga re, omo odun mesan-an (9) mole to si ba sun tipatipa ni Ipinle Edo.
"I don't know what came over me. The devil pushed me to do that.
"I sent her to buy something for me and when she came I only held her.
"But when her parents saw her running out of my premises, they said that I defiled her," oro enu baba getimaanu.
Gege bi alaye awon olopa, won ni baba olomi yalayolo nidi ti jewo, ile ejo ni o si se idajo to ye fun-un.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment