Okunrin omobibi Ipinle Borno to tun un sise gege bi oniroyin alarina laaarin awon omo Boko Haram ati Ijoba apapo, Ahmad Salkida ti kede wi pe digbi ni Abubakar Shekau wa.
Gege bi oro okunrin to fi ilu Dubai se ibujoko, o ni oto ni eni ti won pa. Ati wi pe awonran Abubakar Shekau ko ni eyi ti gbogbo eniyan ri lori ayelukara.
"Mark my words: I have it on authority that Shekau is well and alive.
The picture going round is not the person who torments us with his group." Oro Ahmad Salkida.
Eyin naa le kan si okunrin naa lori ero Twitter fun awon alaye to ba ru yin loju pelu oju opo yii: @ContactSalkida
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment