Smiley face

Akekoo Ile Iwe Giga So Omo Tuntun Sinu Salanga

Nibi ti enikan ti n sunkun airibi ni awon kan ti n gbe omo ti won danu sinu salanga. Omo ile iwe kan ni ilu China lo bimo to si so omo naa sinu salanga leyin to bi omo naa tan lai je ki enikeni mo sii.

Omo tuntun jojolo ti won so sinu salanga naa ha si agbedemeji iho salaga naa eleyii ti igbe ekun re bere si ni pe akiyesi awon eniyan to wa nitosi.

"It was impossible to get the baby out from above. She had fallen into the toilet and gone down the pipes were she had got stuck between the third and fourth floors.

We used an angle grinder to break open the pipeline on the third floor and we could then push the child up to colleagues on the fourth floor where she was handed to medics who were waiting to take her to hospital." Oro enu awon osise panapana ti won fa omo naa yo.

A won olopa ti mu Iya omo naa, won si ti gbe omo tuntun jojolo alailese lorun naa lo si osibitu fun itoju.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment